Skip to content
New issue

Have a question about this project? Sign up for a free GitHub account to open an issue and contact its maintainers and the community.

By clicking “Sign up for GitHub”, you agree to our terms of service and privacy statement. We’ll occasionally send you account related emails.

Already on GitHub? Sign in to your account

scraped bbc yoruba news #23

Open
wants to merge 5 commits into
base: master
Choose a base branch
from

Conversation

sire-ambrose
Copy link

No description provided.

@ruohoruotsi
Copy link
Member

Thank you very much for the PR.

Have these texts been verified as having the correct diacritics (Àmì ohùn)?
I had a quick look and the coverage of correct diacritics looks incomplete. If they are incomplete, I would like to document it before merging, at least so that we know there is extra work that is needed before these texts can be used for NLP tasks.

"Ìdíje bọ̀ọ́lù àwọn obìnrin, WAFCON 2022 gbérasọ ní Morocco"," Oríṣun àwòrán, cafonline Ọjọ keji, oṣu Keje, ọdun 2022, ni idije fun ife ẹyẹ bọọlu awọn obinrin ni Afrika, Women's Africa Cup of Nations, yoo bẹ̀rẹ̀ ni orile-ede Morocco. Ti ọdun yii si ni igba akọkọ ti orile-ede mejila n kopa ninu idije naa. Saaju asiko yii, orile-ede mẹ́jọ lo ma ń kopa. Bakan naa lo jẹ pe igba àkọ́kọ́ re e ti Morocco gbalejo idije naa. Papa ìṣeré mẹta ni yoo ti waye, n'ilu Rabat olu ilu Morocco, ati ilu Casablanca laarin ọjọ keji oṣu Keje, si ọjọ kẹtalelogun, oṣu Keje. Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ akọkọ lati ṣide yoo waye laarin Morocco ati Burkina Faso ni papa isere Prince Moulay Abdellah n'ilu Rabat. Oríṣun àwòrán, caf Ẹgbẹ agbabọọlu Naijiria, Super Falcons, lo gba ife naa ni idije mẹta to kọja, wọn si ti gba a nígbà mẹsan-an, ninu igba mọkanla ti idije naa ti waye. Ipin C ni Naijiria wa ninu idije ti ọdun yii. Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọn àkọ́kọ́ yoo waye lọjọ Aje pẹlu orile-ede South Africa. Lẹyin naa ni wọn o koju Botswana ati Burundi. Ohun kan to jẹ mímọ̀ ni pe lati ìbẹ̀rẹ̀ ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọn àkọ́kọ́, ni Super Falcons ti ma n gba jọba idije. Àwọn agbabọọlu Naijiria to n sisẹ nilẹ okeere, pọ laarin àwọn ọmọ ikọ Super Falcons. Lara wọn ni Asisat Oshoala, ọmọ ẹgbẹ́ agbabọọlu Spain. Oun naa ni balogun ikọ Super Falcons. Ni opin idije WAFCON 2022 yii, ẹgbẹ́ agbabọọlu orile-ede to ba bori yoo ni anfaani lati kopa ni idije ife agbaye lọdun to n bọ. Bakan naa, orile-ede mẹrin to ba de ipele to kangun si aṣekagba, semi-final, yoo ni anfaani lati lọ si Australia ati New Zealand. Ẹgbẹrun lọ́nà ẹẹdẹgbẹta Dọla ni ẹ̀bùn owo ti orile-ede to ba borí ni WAFCON 2022 yoo gba.",2 Agẹmo 2022
Ìjọba Nàìjíríà yí ìpinnu rẹ̀ padà lórí àjọ eré ìdárayá bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ tó bẹ́gilé tẹ́lẹ̀," Oríṣun àwòrán, D'tigers/nigeria basketball Ijọba orile-ede Naijiria ti yi ìpinnu pada lori ere idaraya gbigbabọọlu sáwọn lẹyin ti wọn yoo ọwọ ninu ifieyẹ agbaye losu to lọ.

Ajọ to rí sì ere idaraya ati oun to jọ mọ awọn ọdọ lorile-ede Naijiria ni awọn o ni kopa ninu ifesewonse kankan latari iṣẹlẹ kan to waye ni apa guusu ilẹ adulawo.
Copy link
Member

Choose a reason for hiding this comment

The reason will be displayed to describe this comment to others. Learn more.

Missing Àmì ohùn

@@ -0,0 +1,370 @@
headline,contents,date
Copy link
Member

Choose a reason for hiding this comment

The reason will be displayed to describe this comment to others. Learn more.

Please remove this metadata from the text

Africa to n lọ lọwọ ni Morocco. Eyi waye lẹyin ti wọn lu ẹgbẹ́ agbabọọlu Indomitable
Lionesses ti orile-ede Cameroon ni ami ayo kan si odo. Ọjọbọ ni ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa waye ni papa ìṣeré Mohammed V
n'ilu Casablanca. Ọmi odo ni ẹgbẹ́ agbabọọlu mejeeji ta ní abala àkọ́kọ́ ifẹsẹ̀wọnsẹ̀
naa. Sugbọn nigba ti ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọ isẹju mẹrindinlọgọfa,
Copy link
Member

Choose a reason for hiding this comment

The reason will be displayed to describe this comment to others. Learn more.

The text generally is very raw and need some processing before we can call it a BBC YO NEWS corpus. For starters, it is not better if each new sentence is on a new line?

BBC/columnnDescription Outdated Show resolved Hide resolved
Sign up for free to join this conversation on GitHub. Already have an account? Sign in to comment
Labels
None yet
Projects
None yet
Development

Successfully merging this pull request may close these issues.

None yet

2 participants